Menu

Home page About Us Our Books Blog Contact Us

+234807 983 3768

KIKO YORUBA NI AKOYE 1

Kiko Yoruba Akoye ni ilana eto eko kari-aye. Ede yoruba je okan pataki ninu awon ede abinibi ni agbaye. Ede yoruba, asa yoruba ati ihuwasi awon omo ile yoruba ti di ohun ti won  n ko ni orisirisi ile-eko giga kaakiri agbaye. America ni o, ile Geesi ni o, Russia ni o ati bee bee lo. Eni ti yoo si fun ni ni aso wo, ti orun re la koko wo naa. Eleyi ni o faa ti a o fi gbodo sun asun-wato lori kiko ati kika ede yoruba. Ojoojumo ni imo tuntun n yo ju. Eleyi ni awon agba oje ninu imo lori kiko ati kika ede yoruba fi ko ara won jo lati ko iwe yi ni ona ti yoo fi rorun fun awon omode.

Category: Tags: , ,

Description

Kiko Yoruba Akoye ni ilana eto eko kari-aye. Ede yoruba je okan pataki ninu awon ede abinibi ni agbaye. Ede yoruba, asa yoruba ati ihuwasi awon omo ile yoruba ti di ohun ti won  n ko ni orisirisi ile-eko giga kaakiri agbaye. America ni o, ile Geesi ni o, Russia ni o ati bee bee lo. Eni ti yoo si fun ni ni aso wo, ti orun re la koko wo naa.

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “KIKO YORUBA NI AKOYE 1”

Your email address will not be published.

Top
WhatsApp us