Description
Kiko Yoruba Akoye ni ilana eto eko kari-aye. Ede yoruba je okan pataki ninu awon ede abinibi ni agbaye. Ede yoruba, asa yoruba ati ihuwasi awon omo ile yoruba ti di ohun ti won n ko ni orisirisi ile-eko giga kaakiri agbaye. America ni o, ile Geesi ni o, Russia ni o ati bee bee lo. Eni ti yoo si fun ni ni aso wo, ti orun re la koko wo naa.
Reviews
There are no reviews yet.